Fọ́ọ̀mù Ìforúkọsílẹ̀ — Adéàbẹ̀kẹ́ Fábọ́lá

Pé ẹ̀kún fọ́ọ̀mù náà dáadáa. San N5,000 sí àkọọ́lẹ̀ bébà ní ìsàlẹ̀ kí o sì firanṣẹ́ Ẹ̀rí Ìsánwó sí 0814373742 lórí WhatsApp. Fún ìbéèrè púpọ̀ sí i, pe 09050550688.

Ẹ̀ka Ìdíje (Jọ̀wọ́ Ṣàmì Bí Ó Bá Yẹ)

* Àwọn aaye tí a nílò

Ẹ darapọ̀ mọ́ wa kí a le mú kí èdè Yorùbá máa wà

Bóyá ẹni jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́, olùkọ́, olùwádìí tàbí enití ó fẹràn èdè náà — ayè wà fún yín ní ibí.

Kàn Sí Wá